Your Character is your beauty
22nd September, 2015 Writers
Ìwà le wà

Ìwà le wà
Sé o gbò mi adésewà
Omoge dára bi egbin súgbòn ó buréwà
Ìwà egbin re pó kìkí dé ìlú oba

Adékúnbi okùnrin ogun 
Omo dúro daa gbogbo ara kìkì ògùn
Àlébù ara re ò wa ga bí àpáta won l'ógùn
Níse ló má n janu kiri ó gbàgbé ìtàn ògún

Adétóun elénu so so so
Gbogbo ilé ló mo oo ká bi ayékó otó
Gbogbo ìròyìn lo un tutà bì èlùbó
Kárí ilé ná ti mo o omoge ámèbo

Akinwùnmi omo bàbá ní ilé 
Ó ji na si wáhàlá atí ìpánle
.òrò re ni wó n  so Kárí ilé
Sùgbón kò yé won pé omo jéjé lérè


24981
6
Oyo, Nigeria
  • It's a poem written in basic yoruba language

Average Rating

      Creative

Total Ratings 4

      Super Duper Creative 0
      Super Creative 3
      Creative 1
      Nice Try 0
      You can do better 0