Belle
22nd September, 2015 Writers
 òréke

òréke arewà
Omo dára bi egbin sùgbón kò sí ìwá
Ee ti rí awéléwa
Tí owá so omo birin re di èwà

Gbogbo oúnje omo lórí igbá
Àdùnní omo bàbá ní ìlú ègbá
Tí ilé ìwé so di Sándírà
.ìwà re owá burú bi ti agbanipa 

Suliya omo eléha
Ó ti p'ariwo l'ode gbogbo ohùn ti há
.ìyá n be nílé pèlú ìdùnú omo ní ilé ìwé gíga
Sùgbon oti so ìwà nù omo afaa 

Àntí 'deola  bo o lojà
O gbàgbé ìrètí, ówo okò boo lo ko yà fún mi
Níse le n ko mó lè ni gbogbo ibi ebá ti gbò ijó yá
ìnjé e rò pé elé je àlè àbí aya 

òréke sòwànù óní oun o lori baale

BEAUTY

The beautiful belle
Cute as a deer with a dearth of manners
Have you not seen a siren
Who has turned womanhood to beans

Baby food on display
Adunni, the daughter from egba land
Who has turned sandra in college
Has become as evil as an assassin

Suliya, whose mother veils her face
Outside, Has screamed the top of her voice off
Mother relishes the thought of her child in college
But she, Cleric's own,has lost her manners

Aunty deola, how doth trade?
Have you forgotten ireti, in a situation of do or let me do
You go down low anywhere beat goes
Have you thought you may be the concubine or the wife


Belle loses her manners and screams spinsterhood
19783
15
Oyo, Nigeria
  • Yoruba poem translated in English

Average Rating

      Super Creative

Total Ratings 3

      Super Duper Creative 1
      Super Creative 2
      Creative 0
      Nice Try 0
      You can do better 0